HYMN 763

1.  OLUWA Olugbala jo gba wa la,

     Awa eni mimo l’orun Mimo,

     Awon Angeli si nyo pelu wa,

     Jo da wa lohun.


2.  Bo tile pe Olugbala na yio wa,

     L’ti gba ‘wa elese la,

     Dandan l’Oluwa nso fun wa,

     Jo da wa lohun.


3.  Wa dandan lati da wa l’ohun,

     Awon to tan fitila Mimo Re

     Awon fitila Mimo Re meje,

     Jo da wa lohun.  Amin

English »

Update Hymn