HYMN 771

1.  Mo mbe ninu ododo

     Fun dapo awon eni mimo

     Ewa ninu idapo

     Titi emi o fi pada wa.


2.  Emi kristi lo nso yi

     P’emi o wa danda lotito

     Lati wa se idajo aiye

     Lasi ko ikehin.  Amin 

English »

Update Hymn