HYMN 79

Esin, Oluwa ninu Ijo Mimo yi,

Ijo kan, Mimo ti Baba Orun ni,

K’Oluwa o wa gba awa elese la,

K’O si kawa fikun awon ayanfe Re. Amin

English »

Update Hymn