1. KRISTI Jesu Oba Imole,
To tan imole sinu ijo
yi’ Eje ka sin Oluwa
Olugabala,
Oluwa yio gbo ohun
adura wa.
2. Emi Mimo Olutunu
nba nyin gbe
E gb’orin soke e
korin ayo,
S’Oluwa Kristi Jesu
Oba Imole,
Yi ogbo adura wa yio
si gboebe wa.
3. Michael Mimo
Balogun ‘Jo Mimo,
Yio Segun gbogbo emi esu,
E ko orin iyin si
Oluwa Oba,
Kristi Oba Imole yio
gba nyin la. Amin