1. MIMO, Mimo, Mimo,
Mimo, Mimo, Mimo,
Mimo, Mimo, Mimo,
Jesu wa Mimo ni.
2. E foribale fun,
E foribale fun,
E foribale fun,
Jesu Kristi si omo araiye.
3. Esin Olugbala wa,
Esin Olugbala wa,
Esin Olugbala wa,
Mimo ni Baba wa. Amin.