HYMN 801

1.	Ara e, ba mi kalo,

	Ilekun anu si sile,

	Alabaro kan ko si,

	A fi Jesu nikan.


2.	Ohun lo nsohun gbogbo,

	On pese fun aini wa,

	Nigbati adanwo ba de,

	On lo nsamona wa.  Amin

English »

Update Hymn