HYMN 804

1.  WA gba wa la,

     Baba gba wa la,

     Wa gba wa la,

     Baba gba wa la,

     Ire ni Oluwa, Ire ni

     Oluwa,

     Baba wa gba wa la.


2.  Segun fun wa,

     Baba segun fun wa,

     Segun fun wa,

     Baba segun fun wa,

     Ire ni Oluwa, Ire ni

     Oluwa,

     Baba segun fun wa.


3.  Dabobo bo wa,

     Baba dabo bo wa,

     Dabo bo wa,

     Ire ni Oluwa, Ire ni

     Oluwa

     Baba dabo bo wa.


4.  Wa bukun wa,

     Baba wa bukun wa,

     Wa bukun wa,

     Baba wa bukun wa,

     Ire ni Oluwa, Ire ni

     Oluwa.

     Baba wa bukun wa.  Amin


English »

Update Hymn