HYMN 809

1.  OLORUN mi ni'le

     Olorun mi ni’rin ajo,

     Olorun mi lo ‘san,

     Olorun mi lo'ru,

     Ogo! Ogo! Ogo!

     Fun Jehovah.


2.  Dabobo wa ni ‘le,

     Dabobo wa ni ‘rin ajo,

     Dabobo wa losan,

     Dabobo wa l'oru,

     Ogo! Ogo! Ogo!

     Fun Jehovah.


3.  Samo na wa ni ‘le,

     Samona wa ni ‘rin ajo,

     Samona wa l’osan,

     Samona wa l’oru,

     Ogo! Ogo! Ogo!

     Fun Jehovah.


4.  Pese fun wa n’ile,

     Pese fun wa ni’rin ajo,

     Pese fun wa l’osan,

     Pese fun wa l’oru,

     Ogo! Ogo! Ogo!

     Fun Jehovah.


5.  Segun fun wa n’ile,

     Segun fun wa ni ‘rin ajo,

     Segun fun we l'osan,

     Segun fun wa l’oru,

     Ogo! Ogo! Ogo!

     Fun Jehovah.


6.  Bukun fun wa ni ‘le,

     Bukun fun wa ni ‘rin ajo,

     Bukun fun wa l’osan,

     Bukun fun wa l’oru,

     Ogo! Ogo! Ogo!

     Fun Jehovah.  Amin



English »

Update Hymn