1. ESIN Olorun, Esin Olorun,
Oba Imole araiye,
Didan ninu gbogbo ogo.
2. E mura lati sin Oluwa
ninu ijo Mimo,
Aiyeraye Oba Imole,
Yio gba wa n'u gbekun aiye.
3. E je k'a sin Olorun
E je k'a sin Olorun
Aiyeraye Oba Imole
Yio wa pelu wa loni. Amin