1. MALEKA Mimo
wo’nu ile mi wa,
Emiti sorire, Babalo
so fun mi,
Maleka mimo wo ‘nu
ile mi wa,
Lati wa bami sere.
2. Elmorijah ti de lati wa
bukun mi,
Emi ti sorire, Baba
loso fun mi,
Elmorijah ti de latiwa
bukun mi,
Elmorijah ti wole de. Amin