HYMN 829

JESU awa de sinu Ile Re,

Wa sarin wa lati bukun wa,

Omode niwa, awa ko mokan,

Gbowo Re le wa, si sure funwa,

Elese ni wa, awa ko mokan,

Gbo owo Re le wa, si sanu ‘funwa,

Dari ese ji wa, So wa di Mimo,

Gbo owo re le wa si

fa wa mora.  Amin


English »

Update Hymn