HYMN 852

ABI Kristi fun wa

loni ni Bethlehem,

Awon ‘rawo Orun, Won mbu si ayo,

Awon ‘rawo Orun, Won mbu si ayo,

F’Olugbala to wa,

Lati ko ese aiye lo,

F’Olugbala to wa,

Lati ko ese aiye lo,

Enyin Angeli Mimo t’Orun,

E bu sayo pelu,

Awon ‘rawo mimo t’Orun.  Amin



English »

Update Hymn