HYMN 877

1.  JESU l’ojo anu yi,

     Awon agan nwo oju Re,

     To r’ekun kikoro won,

     Ma je k’agan ‘fe re.


2.  Wakati na de kankan,

     A wole lor ’ekun wa,

     Ma jeka pofo laiye,

     F’omo rere fun wa.  Amin

English »

Update Hymn