1. IMOLE Kristi tan Halleluya,
Halleluya, Halleluya,
Halleluya.
2. Korin Iwo agan, Korin
t’omo titun,
Korin f’omo titun,
Korin f’omo titun,
Korin f'omo titun.
3. Lori ite lati mu fun o wa,
Lati mufun o wa, lati
mu fun o wa,
Lati mu fun o wa. Amin