HYMN 926

KO Oba ko sokale,

Ko wa gbawa loni

K’o Oba Mimo k’o sokale

Kowa gbawa la loni

Ninu ijo mimo yii lonii

Ko wa d’emi gigun si

fun wa.  Amin




English »

Update Hymn