HYMN 930

MOSE si wa lo si Kanaan,

MOSE si wa lo si Kanaan,

Alejo l'awa nse

Awa arinrinajo

Mose si wa lo si Kanaan,

O pe wa, O pe wa, O pe wa,

O pe wa S’Ile Mimo

O pe wa, O pe wa,

O pe wa,

O pe wa si Celestial.  Amin

English »

Update Hymn