1. SEGUN fun wa,
Baba segun fun wa,
Segun fun wa, Baba
segun fun wa,
Ire ni Oluwa, Ire ni Oluwa,
Baba Segun fun wa.
2. Wa wo wa san, Baba
wa wo wa san,
Wa wo wa san, Baba
wa wo wa san,
Ire ni Oluwa, Ire ni Oluwa,
Baba wa wo wa san.
3. Gbase wa se,
Baba gbase wa se,
Gbase wa se,
Baba gbase wa se,
Ire ni Oluwa, Ire ni Oluwa
Baba gbase wa se.
4. Wa bukun wa, Baba
wa bukun wa
Wa bukun wa, Baba
wa bukun wa
Ire ni Oluwa, Ire ni Oluwa
Baba wa bukun wa. Amin