Chorus: Emi asin Kristi,
Emi a sin Kristi,
Oba iye ni ma sin
titi aiye.
1. OBA Celestial, Oba iyanu,
Oba Celestial, Olododo,
Olugbeja.
Chorus: Emi a sin Kristi...
2. O te gbogbo idamu mo’le,
Ninu idamu O mu ayo kun.
Chorus: Emi a sin Kristi... Amin