1. MO ti ba Jesu lo s'ode
Mo ti ba Jesu lo s'ode
Esu d'ele ko ba mi n'ile
Mo ti ba Jesu lo s’ode.
2. Jesu Kristi wa pelu mi
Jesu Kristi wa pelu mi
Orunko Re l’alye mo mi mo
Jesu Kristi wa pelu mi.
3. Monlo s’ijo Celestial
Monlo s’ijo Celestial
Egberun ljo sa lo mbe laiye
Monlo s’ijo Celestial.
4. O ti d’oju t’awon aje
O ti d’oju ti awon aje
Jesu Kristi lo da mi lare
O ti d’oju t’awon oso. Amin