HYMN 970

ONA igbala odo Jesu Oluwa

Olugbala lo wa,

Aiye ati ododo,

T’Oluwa dun,

Oruko Jesu Oluwa

O to gba ni, Ara gbagbo,

Ara gbaa gbo,

Lati gba ade ogo.  Amin


English »

Update Hymn