1. A TI segun esu,
Ati bori won,
Ati bori segun esu,
Ati bori won,
Esu ko ni agbara lori
Ijo Mimo.
2. Ati t’aje mo’le
Ati bori won
Ati t’aje mo’le
Ati bori won
Ajeko ni agbara l’ori
Ijo Mimo.
3. Ati t’oso mo’le
Ati bori won
Ati t’oso mo’le
Ati bori won
Oso ko ni agbara l’ori
Ijo Mimo. Amin